caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Ash-Sharh الشرح

8 verses · Mecca · revelation order 12

بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ أَلَمْ نَشْرَحْ لَكَ صَدْرَكَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelṢé A kò ṣípayá igbá-àyà rẹ fún ọ bí?

See all translations of this verse →

وَوَضَعْنَا عَنكَ وِزْرَكَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelA sì gbé ẹ̀ṣẹ̀ rẹ kúrò lọ́rùn rẹ,

See all translations of this verse →

ٱلَّذِىٓ أَنقَضَ ظَهْرَكَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelèyí tí ó wọ̀ ọ́ lọ́rùn.[1]

See all translations of this verse →

وَرَفَعْنَا لَكَ ذِكْرَكَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelA sì gbé ìrántí orúkọ rẹ ga fún ọ.

See all translations of this verse →

فَإِنَّ مَعَ ٱلْعُسْرِ يُسْرًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNítorí náà, dájúdájú ìdẹ̀kùn wà lẹ́yìn ìnira.

See all translations of this verse →

إِنَّ مَعَ ٱلْعُسْرِ يُسْرًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú ìdẹ̀kùn wà lẹ́yìn ìnira sẹ́.

See all translations of this verse →

فَإِذَا فَرَغْتَ فَٱنصَبْ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNítorí náà, nígbà tí o bá bùṣe (lórí ohun tí ó jẹmọ́ táyé), gbìyànjú (dáadáa lórí ìjọ́sìn).

See all translations of this verse →

وَإِلَىٰ رَبِّكَ فَٱرْغَب

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelỌ̀dọ̀ Olúwa rẹ sì ni kí o ṣojú kòkòrò oore sí.

See all translations of this verse →

Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70