caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Qaari'a القارعة

11 verses · Mecca · revelation order 30

بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ ٱلْقَارِعَةُ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÀkókò ìjáyà.

See all translations of this verse →

مَا ٱلْقَارِعَةُ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelKí ni Àkókò ìjáyà?

See all translations of this verse →

وَمَآ أَدْرَىٰكَ مَا ٱلْقَارِعَةُ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelKí sì l’ó mú ọ mọ ohun tó ń jẹ́ Àkókò ìjáyà?

See all translations of this verse →

يَوْمَ يَكُونُ ٱلنَّاسُ كَٱلْفَرَاشِ ٱلْمَبْثُوثِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael(Òhun ni) ọjọ́ tí ènìyàn yó dà bí àfòpiná tí wọ́n fọ́nká síta,

See all translations of this verse →

وَتَكُونُ ٱلْجِبَالُ كَٱلْعِهْنِ ٱلْمَنفُوشِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelàwọn àpáta yó sì dà bí ẹ̀gbọ̀n òwú tí wọ́n gbọ̀n dànù.

See all translations of this verse →

فَأَمَّا مَن ثَقُلَتْ مَوَٰزِينُهُۥ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNítorí náà, ní ti ẹni tí òṣùwọ̀n (iṣẹ́ rere) rẹ̀ bá tẹ̀wọ̀n,

See all translations of this verse →

فَهُوَ فِى عِيشَةٍ رَّاضِيَةٍ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaeló sì máa wà nínú ìṣẹ̀mí tó máa yọ́nú sí.

See all translations of this verse →

وَأَمَّا مَنْ خَفَّتْ مَوَٰزِينُهُۥ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNí ti ẹni tí òṣùwọ̀n (iṣẹ́ rere) rẹ̀ bá sì fúyẹ́,

See all translations of this verse →

فَأُمُّهُۥ هَاوِيَةٌ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelHāwiyah sì ni ibùgbé rẹ̀.

See all translations of this verse →

وَمَآ أَدْرَىٰكَ مَا هِيَهْ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelKí sì ni ó mú ọ mọ ohun tó ń jẹ́ bẹ́ẹ̀?

See all translations of this verse →

نَارٌ حَامِيَةٌۢ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael(Òhun ni) Iná gbígbóná tó ń jó gan-an.

See all translations of this verse →

Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70