caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà An-Naas الناس

6 verses · Mecca · revelation order 21

بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ قُلْ أَعُوذُ بِرَبِّ ٱلنَّاسِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelSọ pé: “Mo sá di Olúwa àwọn ènìyàn,

See all translations of this verse →

مَلِكِ ٱلنَّاسِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelỌba àwọn ènìyàn,

See all translations of this verse →

إِلَٰهِ ٱلنَّاسِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelỌlọ́hun àwọn ènìyàn,[1]

See all translations of this verse →

مِن شَرِّ ٱلْوَسْوَاسِ ٱلْخَنَّاسِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelníbi aburú (aṣ-Ṣaetọ̄n) oníròyíròyí, olùsásẹ́yìn (fún ẹni tó bá ń dárúkọ Allāhu[1]).

See all translations of this verse →

ٱلَّذِى يُوَسْوِسُ فِى صُدُورِ ٱلنَّاسِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael(aṣ-Ṣaetọ̄n ni) ẹni tí ó ń kó ròyíròyí sínú àwọn ọkàn ènìyàn.

See all translations of this verse →

مِنَ ٱلْجِنَّةِ وَٱلنَّاسِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael(Ṣaetọ̄n náà) wà nínú àwọn àlùjànnú àti àwọn ènìyàn.”

See all translations of this verse →

Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70