caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Falaq الفلق

5 verses · Mecca · revelation order 20

بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ قُلْ أَعُوذُ بِرَبِّ ٱلْفَلَقِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelSọ pé: “Mo sá di Olúwa òwúrọ̀ kùtùkùtù

See all translations of this verse →

مِن شَرِّ مَا خَلَقَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelníbi aburú ohun tí Ó dá,[1]

See all translations of this verse →

وَمِن شَرِّ غَاسِقٍ إِذَا وَقَبَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelàti níbi aburú òru nígbà tí ó bá ṣóòkùn,

See all translations of this verse →

وَمِن شَرِّ ٱلنَّفَّٰثَٰتِ فِى ٱلْعُقَدِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelàti níbi aburú àwọn (òpìdán) tó ń fẹnu fátẹ́gùn túẹ́túẹ́ sínú àwọn ońdè,

See all translations of this verse →

وَمِن شَرِّ حَاسِدٍ إِذَا حَسَدَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelàti níbi aburú onílara nígbà tí ó bá ṣe ìlara.”

See all translations of this verse →

Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70