caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Humaza الهمزة

9 verses · Mecca · revelation order 32

بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ وَيْلٌ لِّكُلِّ هُمَزَةٍ لُّمَزَةٍ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÈgbé ni fún gbogbo abúnilójú-ẹni, abúnilẹ́yìn-ẹni,

See all translations of this verse →

ٱلَّذِى جَمَعَ مَالًا وَعَدَّدَهُۥ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelẹni tí ó kó dúkìá jọ, tí ó sì kà á lákàtúnkà (láì ná an fún ẹ̀sìn).

See all translations of this verse →

يَحْسَبُ أَنَّ مَالَهُۥٓ أَخْلَدَهُۥ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÓ ń lérò pé dájúdájú dúkìá rẹ̀ yóò mú un ṣe gbére (nílé ayé).

See all translations of this verse →

كَلَّا لَيُنۢبَذَنَّ فِى ٱلْحُطَمَةِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelRárá (kò rí bẹ́ẹ̀). Dájúdájú wọ́n máa kù ú lókò sínú Hutọmọh ni.

See all translations of this verse →

وَمَآ أَدْرَىٰكَ مَا ٱلْحُطَمَةُ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelKí sì ni ó mú ọ mọ ohun tó ń jẹ́ Hutọmọh?

See all translations of this verse →

نَارُ ٱللَّهِ ٱلْمُوقَدَةُ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael(Òhun ni) Iná Allāhu tí wọ́n ń kò (tó ń jó geregere),

See all translations of this verse →

ٱلَّتِى تَطَّلِعُ عَلَى ٱلْأَفْـِٔدَةِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelèyí tí ó máa jó (ẹ̀dá) wọ inú ọkàn lọ.

See all translations of this verse →

إِنَّهَا عَلَيْهِم مُّؤْصَدَةٌ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú wọ́n máa ti (àwọn ìlẹ̀kùn) Iná pa mọ́ wọn lórí pátápátá.

See all translations of this verse →

فِى عَمَدٍ مُّمَدَّدَةٍۭ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael(Wọ́n máa wà) láààrin àwọn òpó kìrìbìtì gíga (nínú Iná).

See all translations of this verse →

Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70