caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Asr العصر

3 verses · Mecca · revelation order 13

بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ وَٱلْعَصْرِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelAllāhu fi àkókò ìrọ̀lẹ́ ayé búra.

See all translations of this verse →

إِنَّ ٱلْإِنسَٰنَ لَفِى خُسْرٍ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú ènìyàn wà nínú òfò.

See all translations of this verse →

إِلَّا ٱلَّذِينَ ءَامَنُوا۟ وَعَمِلُوا۟ ٱلصَّٰلِحَٰتِ وَتَوَاصَوْا۟ بِٱلْحَقِّ وَتَوَاصَوْا۟ بِٱلصَّبْرِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÀyàfi àwọn tó gbàgbọ́ ní òdodo, tí wọ́n ṣe àwọn iṣẹ́ rere, tí wọ́n sọ àsọtẹ́lẹ̀ òdodo láààrin ara wọn, tí wọ́n sì tún sọ àsọtẹ́lẹ̀ sùúrù láààrin ara wọn.

See all translations of this verse →

Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70