caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Fil الفيل

5 verses · Mecca · revelation order 19

بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ أَلَمْ تَرَ كَيْفَ فَعَلَ رَبُّكَ بِأَصْحَٰبِ ٱلْفِيلِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelṢé o kò wòye sí bí Olúwa rẹ ti ṣe ọ̀rọ̀ ìjọ elérin ni?

See all translations of this verse →

أَلَمْ يَجْعَلْ كَيْدَهُمْ فِى تَضْلِيلٍ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelṢé kò sọ ète wọn di òfo àti anù bí?

See all translations of this verse →

وَأَرْسَلَ عَلَيْهِمْ طَيْرًا أَبَابِيلَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÓ sì rán àwọn ẹyẹ níkọ̀níkọ̀ sí wọn.

See all translations of this verse →

تَرْمِيهِم بِحِجَارَةٍ مِّن سِجِّيلٍ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelWọ́n ń jù wọ́n ní òkúta amọ̀ (tó ti gbaná sára).

See all translations of this verse →

فَجَعَلَهُمْ كَعَصْفٍ مَّأْكُولٍۭ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÓ sì sọ wọ́n di bíi pòpórò gbígbẹ tí ẹranko jẹ lájẹdàsílẹ̀.

See all translations of this verse →

Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70