caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Masad المسد

5 verses · Mecca · revelation order 6

بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ تَبَّتْ يَدَآ أَبِى لَهَبٍ وَتَبَّ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelỌwọ́ Abu-Lahab méjèèjì ti ṣòfò. Òun náà sì ṣòfò.

See all translations of this verse →

مَآ أَغْنَىٰ عَنْهُ مَالُهُۥ وَمَا كَسَبَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÀwọn dúkìá rẹ̀ àti ohun tí ó ṣe níṣẹ́ (ìyẹn, àwọn ọmọ rẹ̀) kò sì níí rọ̀ ọ́ lọ́rọ̀ (níbi ìyà).

See all translations of this verse →

سَيَصْلَىٰ نَارًا ذَاتَ لَهَبٍ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÓ sì máa wọ inú Iná eléjò fòfò.

See all translations of this verse →

وَٱمْرَأَتُهُۥ حَمَّالَةَ ٱلْحَطَبِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÀti ìyàwó rẹ̀, aláàárù-igi-ìṣẹ́pẹ́ ẹlẹ́gùn-ún, (ó máa wọná).

See all translations of this verse →

فِى جِيدِهَا حَبْلٌ مِّن مَّسَدٍۭ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelIgbà-ọ̀pẹ pọ̀npọ̀nràn máa wà ní ọrùn rẹ̀ (nínú Iná).

See all translations of this verse →

Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70