caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Maa'un الماعون

7 verses · Mecca · revelation order 17

بِسْمِ ٱللَّهِ ٱلرَّحْمَٰنِ ٱلرَّحِيمِ أَرَءَيْتَ ٱلَّذِى يُكَذِّبُ بِٱلدِّينِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelSọ fún mi nípa ẹni tó ń pe Ọjọ́ Ẹ̀san ní irọ́!

See all translations of this verse →

فَذَٰلِكَ ٱلَّذِى يَدُعُّ ٱلْيَتِيمَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÌyẹn ni ẹni tó ń lé ọmọ-òrukàn dànù.

See all translations of this verse →

وَلَا يَحُضُّ عَلَىٰ طَعَامِ ٱلْمِسْكِينِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelKò sì níí gbìyànjú láti bọ́ mẹ̀kúnnù.

See all translations of this verse →

فَوَيْلٌ لِّلْمُصَلِّينَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÈgbé ni fún àwọn (mùnááfìkí) tó ń kírun;[1]

See all translations of this verse →

ٱلَّذِينَ هُمْ عَن صَلَاتِهِمْ سَاهُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelàwọn tó ń gbàgbé láti kírun wọn ní àsìkò rẹ̀;

See all translations of this verse →

ٱلَّذِينَ هُمْ يُرَآءُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelàwọn tó ń ṣe ṣekárími;

See all translations of this verse →

وَيَمْنَعُونَ ٱلْمَاعُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelàti pé wọ́n ń hánnà ohun èlò (fún àwọn ènìyàn).

See all translations of this verse →

Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70