إِلَّا عِبَادَكَ مِنْهُمُ ٱلْمُخْلَصِينَ Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelàfi àwọn ẹrúsìn Rẹ nínú wọn, àwọn tí O ṣà lẹ́ṣà (fún ìgbàgbọ́ òdodo).”[1]