وَإِخْوَٰنُهُمْ يَمُدُّونَهُمْ فِى ٱلْغَىِّ ثُمَّ لَا يُقْصِرُونَ
Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael(Àmọ́ ní ti) àwọn ọmọ ìyá (aṣ-Ṣaetọ̄n), ńṣe ni àwọn aṣ-Ṣaetọ̄n yóò máa kún wọn lọ́wọ́ nínú ìṣìnà. Lẹ́yìn náà, wọn kò sì níí dáràn mọ níwọ̀n.