caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Qalam, ẹsẹ 50

Mecca · revelation order 2 · 68:50

فَٱجْتَبَٰهُ رَبُّهُۥ فَجَعَلَهُۥ مِنَ ٱلصَّٰلِحِينَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNítorí náà, Olúwa rẹ̀ ṣà á lẹ́ṣà. Ó sì ṣe é ní ara àwọn ẹni rere.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70