caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Qalam, ẹsẹ 49

Mecca · revelation order 2 · 68:49

لَّوْلَآ أَن تَدَٰرَكَهُۥ نِعْمَةٌ مِّن رَّبِّهِۦ لَنُبِذَ بِٱلْعَرَآءِ وَهُوَ مَذْمُومٌ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelTí kò bá jẹ́ pé ìkẹ́ kan láti ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ̀ lé e bá, wọn ìbá jù ú sórí ilẹ̀ gban̄sasa (láti inú ẹja) ní ẹni-èébú.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70