caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Waaqia, ẹsẹ 61

Mecca · revelation order 46 · 56:61

عَلَىٰٓ أَن نُّبَدِّلَ أَمْثَٰلَكُمْ وَنُنشِئَكُمْ فِى مَا لَا تَعْلَمُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelláti yí irú yín padà (láti inú erùpẹ̀ sí alààyè), kí á sì ṣẹ̀dá yín (ní ọ̀tun) sínú ohun tí ẹ kò mọ̀ (nínú àwọn ìrísí).
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70