caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Ad-Dukhaan, ẹsẹ 54

Mecca · revelation order 64 · 44:54

كَذَٰلِكَ وَزَوَّجْنَٰهُم بِحُورٍ عِينٍ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelBáyẹn (ni ọ̀rọ̀ wọn yó ṣe rí). A sì máa fi àwọn obìnrin ẹlẹ́yinjú-ẹgẹ́ ṣe ìyàwó fún wọn.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70