caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Ad-Dukhaan, ẹsẹ 12

Mecca · revelation order 64 · 44:12

رَّبَّنَا ٱكْشِفْ عَنَّا ٱلْعَذَابَ إِنَّا مُؤْمِنُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael(Àwọn ènìyàn yóò wí pé): Olúwa wa, gbé ìyà náà kúrò fún wa, dájúdájú àwa yóò gbàgbọ́ ní òdodo.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70