فَلَمَّآ ءَاتَىٰهُم مِّن فَضْلِهِۦ بَخِلُوا۟ بِهِۦ وَتَوَلَّوا۟ وَّهُم مُّعْرِضُونَ
Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÀmọ́ nígbà tí Ó fún wọn nínú oore àjùlọ Rẹ̀, wọ́n ṣahun pẹ̀lú rẹ̀. Wọ́n pẹ̀yìndà, wọ́n sì ń gbúnrí (láti náwó fẹ́sìn).