caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Muzzammil, ẹsẹ 14

Mecca · revelation order 3 · 73:14

يَوْمَ تَرْجُفُ ٱلْأَرْضُ وَٱلْجِبَالُ وَكَانَتِ ٱلْجِبَالُ كَثِيبًا مَّهِيلًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNí ọjọ́ tí ilẹ̀ àti àwọn àpáta yóò máa mì tìtì. Àwọn àpáta sì máa di yanrìn tí wọ́n kójọ tí wọ́n túká.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70