caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Jinn, ẹsẹ 9

Mecca · revelation order 40 · 72:9

وَأَنَّا كُنَّا نَقْعُدُ مِنْهَا مَقَٰعِدَ لِلسَّمْعِ فَمَن يَسْتَمِعِ ٱلْـَٔانَ يَجِدْ لَهُۥ شِهَابًا رَّصَدًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú àwa máa ń jókòó síbẹ̀ ní àwọn ibùdó kan fún gbígbọ́ ọ̀rọ̀. Ṣùgbọ́n ẹni tó bá jọ́rọ̀ gbọ́ lásìkò yìí, ó máa rí ògúnná tó ti lúgọ dè é.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70