caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Jinn, ẹsẹ 18

Mecca · revelation order 40 · 72:18

وَأَنَّ ٱلْمَسَٰجِدَ لِلَّهِ فَلَا تَدْعُوا۟ مَعَ ٱللَّهِ أَحَدًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú àwọn mọ́sálásí ń jẹ́ ti Allāhu.[1] Nítorí náà, ẹ kò gbọ́dọ̀ pe ẹnì kan pẹ̀lú Allāhu.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70