caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Jinn, ẹsẹ 16

Mecca · revelation order 40 · 72:16

وَأَلَّوِ ٱسْتَقَٰمُوا۟ عَلَى ٱلطَّرِيقَةِ لَأَسْقَيْنَٰهُم مَّآءً غَدَقًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÀti pé tí ó bá jẹ́ pé wọ́n dúró ṣinṣin lójú ọ̀nà (’Islām) ni, dájúdájú Àwa ìbá fún wọn ní omi púpọ̀ mu.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70