caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Qaaf, ẹsẹ 21

Mecca · revelation order 34 · 50:21

وَجَآءَتْ كُلُّ نَفْسٍ مَّعَهَا سَآئِقٌ وَشَهِيدٌ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelẸ̀mí kọ̀ọ̀kan yóò wá pẹ̀lú olùdarí kan àti ẹlẹ́rìí kan (nínú àwọn mọlāika).
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70