caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Qaaf, ẹsẹ 17

Mecca · revelation order 34 · 50:17

إِذْ يَتَلَقَّى ٱلْمُتَلَقِّيَانِ عَنِ ٱلْيَمِينِ وَعَنِ ٱلشِّمَالِ قَعِيدٌ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael(Rántí) nígbà tí (mọlāika) àwọn olùgbọ̀rọ̀-sílẹ̀ méjì bá bẹ̀rẹ̀sí gba ọ̀rọ̀ (sílẹ̀), tí ọ̀kan jókòó sí ọ̀tún, tí ọ̀kan jókòó sí òsì.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70