فِيهَا يُفْرَقُ كُلُّ أَمْرٍ حَكِيمٍ Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNínú òru náà ni wọ́n ti máa yanjú gbogbo ọ̀rọ̀ tí kò níí tàsé (lórí ẹ̀dá).