caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Ad-Dukhaan, ẹsẹ 38

Mecca · revelation order 64 · 44:38

وَمَا خَلَقْنَا ٱلسَّمَٰوَٰتِ وَٱلْأَرْضَ وَمَا بَيْنَهُمَا لَٰعِبِينَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelA kò ṣẹ̀dá àwọn sánmọ̀ àti ilẹ̀ àti ohunkóhun tí ń bẹ láààrin méjèèjì pẹ̀lú eré ṣíṣe.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70