كَمْ تَرَكُوا۟ مِن جَنَّٰتٍ وَعُيُونٍ Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelMélòó mélòó nínú àwọn ọgbà oko àti odò ìṣẹ́lẹ̀rú tí wọ́n fi sílẹ̀ (lẹ́yìn ìparun wọn).