فَكَذَّبُوهُ فَإِنَّهُمْ لَمُحْضَرُونَ Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelWọ́n sì pè é ní òpùrọ́. Nítorí náà, wọ́n máa mú wọn wá sínú Iná.