caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Qasas, ẹsẹ 11

Mecca · revelation order 49 · 28:11

وَقَالَتْ لِأُخْتِهِۦ قُصِّيهِ فَبَصُرَتْ بِهِۦ عَن جُنُبٍ وَهُمْ لَا يَشْعُرُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÓ sì sọ fún arábìnrin rẹ̀ pé: “Tọ ipa rẹ̀ lọ.” Ó sì ń wò ó láti ibi tó jìnnà. Wọn kò sì fura (sí i).
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70