caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Maryam, ẹsẹ 84

Mecca · revelation order 44 · 19:84

فَلَا تَعْجَلْ عَلَيْهِمْ إِنَّمَا نَعُدُّ لَهُمْ عَدًّا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNítorí náà, má ṣe kánjú nípa (ìyà) wọn. A kúkú ń ka (ọjọ́) fún wọn ní kíkà tààrà.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70