caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Maryam, ẹsẹ 83

Mecca · revelation order 44 · 19:83

أَلَمْ تَرَ أَنَّآ أَرْسَلْنَا ٱلشَّيَٰطِينَ عَلَى ٱلْكَٰفِرِينَ تَؤُزُّهُمْ أَزًّا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelṢé ìwọ kò wòye pé dájúdájú Àwa ń dẹ àwọn aṣ-ṣaetọ̄n sí àwọn aláìgbàgbọ́ ni, tí wọ́n sì ń gùn wọ́n gan-an (síbi ẹ̀ṣẹ̀)?
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70