caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Maryam, ẹsẹ 40

Mecca · revelation order 44 · 19:40

إِنَّا نَحْنُ نَرِثُ ٱلْأَرْضَ وَمَنْ عَلَيْهَا وَإِلَيْنَا يُرْجَعُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú Àwa l’A máa jogún ilẹ̀ àti àwọn tó ń bẹ lórí rẹ̀. Ọ̀dọ̀ Wa sì ni wọn yóò dá wọn padà sí.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70