caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà An-Nahl, ẹsẹ 37

Mecca · revelation order 70 · 16:37

إِن تَحْرِصْ عَلَىٰ هُدَىٰهُمْ فَإِنَّ ٱللَّهَ لَا يَهْدِى مَن يُضِلُّ وَمَا لَهُم مِّن نَّٰصِرِينَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelTí o bá ń ṣojú kòkòrò sí ìmọ̀nà wọn, dájúdájú Allāhu, ẹni tí Ó bá ṣì lọ́nà, kò níí mọ̀nà,[1] kò sì níí sí àwọn alárànṣe kan kan fún wọn.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70