وَلَسَوْفَ يُعْطِيكَ رَبُّكَ فَتَرْضَىٰٓ Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú láìpẹ́ Olúwa rẹ máa fún ọ ní (oore púpọ̀ ní ọ̀run). Nítorí náà, o sì máa yọ́nú sí i.