وَإِذَا ٱلْقُبُورُ بُعْثِرَتْ Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelàti (nígbà tí A bá ta ilẹ̀ sókè), tí A sì mú àwọn òkú jáde (láàyè) láti inú àwọn sàréè,