وَإِذَا ٱلنُّفُوسُ زُوِّجَتْ Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelàti nígbà tí wọ́n bá so àwọn ẹ̀mí pọ̀ mọ́ra wọn, (ẹni rere pẹ̀lú ẹni rere, ẹni ibi pẹ̀lú ẹni ibi)