وَإِذَا ٱلرُّسُلُ أُقِّتَتْ Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelàti nígbà tí wọ́n bá fún àwọn Òjíṣẹ́ ní àsìkò láti kójọ (pẹ̀lú ìjọ wọn),