caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Insaan, ẹsẹ 15

Medina · revelation order 98 · 76:15

وَيُطَافُ عَلَيْهِم بِـَٔانِيَةٍ مِّن فِضَّةٍ وَأَكْوَابٍ كَانَتْ قَوَارِيرَا۠

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÀti pé wọn yóò máa gbé ife ìmumi ńlá tí wọ́n ṣe láti ara fàdákà àti àwọn ife ìmumi kékeré tí ó jẹ́ aláwo káà kiri ọ̀dọ̀ wọn.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70