caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Muzzammil, ẹsẹ 9

Mecca · revelation order 3 · 73:9

رَّبُّ ٱلْمَشْرِقِ وَٱلْمَغْرِبِ لَآ إِلَٰهَ إِلَّا هُوَ فَٱتَّخِذْهُ وَكِيلًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelOlúwa ibùyọ òòrùn àti ibùwọ̀ òòrùn, kò sí ọlọ́hun kan tí ẹ gbọ́dọ̀ jọ́sìn fún ní ọ̀nà òdodo àfi Òun. Nítorí náà, mú Un ní Aláfẹ̀yìntì.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70