caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Jinn, ẹsẹ 7

Mecca · revelation order 40 · 72:7

وَأَنَّهُمْ ظَنُّوا۟ كَمَا ظَنَنتُمْ أَن لَّن يَبْعَثَ ٱللَّهُ أَحَدًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú àwọn àlùjànnú lérò gẹ́gẹ́ bí ẹ̀yin ènìyàn náà ṣe lérò pé, Allāhu kò níí gbé ẹnì kan kan dìde (lẹ́yìn ikú).
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70