caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Jinn, ẹsẹ 14

Mecca · revelation order 40 · 72:14

وَأَنَّا مِنَّا ٱلْمُسْلِمُونَ وَمِنَّا ٱلْقَٰسِطُونَ فَمَنْ أَسْلَمَ فَأُو۟لَٰٓئِكَ تَحَرَّوْا۟ رَشَدًا

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú àwọn mùsùlùmí wà nínú wa. Àwọn arúfin náà wà nínú wa. Nítorí náà, ẹnikẹ́ni tí ó bá ṣe ’Islām, àwọn wọ̀nyẹn ni wọ́n ṣe àwárí ìmọ̀nà.”
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70