caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-A'raaf, ẹsẹ 174

Mecca · revelation order 39 · 7:174

وَكَذَٰلِكَ نُفَصِّلُ ٱلْـَٔايَٰتِ وَلَعَلَّهُمْ يَرْجِعُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelBáyẹn ni A ṣe ń ṣàlàyé àwọn āyah Wa, nítorí kí wọ́n lè ṣẹ́rí padà (síbi òdodo).
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70