فَلَآ أُقْسِمُ بِمَوَٰقِعِ ٱلنُّجُومِ Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelNítorí náà, Mò ń fi àwọn àyè tí ìkọ̀ọ̀kan gbólóhùn al-Ƙur’ān wà nínú sánmọ̀ búra.[1]