caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Waaqia, ẹsẹ 47

Mecca · revelation order 46 · 56:47

وَكَانُوا۟ يَقُولُونَ أَئِذَا مِتْنَا وَكُنَّا تُرَابًا وَعِظَٰمًا أَءِنَّا لَمَبْعُوثُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelWọ́n sì máa ń wí pé: “Ṣé nígbà tí a bá di òkú, tí a sì di erùpẹ̀ àti egungun, ǹjẹ́ Wọn yóò tún gbé wa dìde ni?
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70