caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Waaqia, ẹsẹ 18

Mecca · revelation order 46 · 56:18

بِأَكْوَابٍ وَأَبَارِيقَ وَكَأْسٍ مِّن مَّعِينٍ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikaelpẹ̀lú àwọn ife omi, ohun ìrọmi fẹ̀ǹfẹ̀ àti ife ọtí aládùn láti inú odò kan tó ń ṣàn (káà kiri ọ̀dọ̀ wọn).
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70