caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà At-Tur, ẹsẹ 35

Mecca · revelation order 76 · 52:35

أَمْ خُلِقُوا۟ مِنْ غَيْرِ شَىْءٍ أَمْ هُمُ ٱلْخَٰلِقُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelTàbí wọ́n ṣẹ̀dá wọn láì sí Aṣẹ̀dá? Tàbí àwọn ni wọ́n ṣẹ̀dá ara wọn ni?
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70