caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Qaaf, ẹsẹ 45

Mecca · revelation order 34 · 50:45

نَّحْنُ أَعْلَمُ بِمَا يَقُولُونَ وَمَآ أَنتَ عَلَيْهِم بِجَبَّارٍ فَذَكِّرْ بِٱلْقُرْءَانِ مَن يَخَافُ وَعِيدِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÀwa nímọ̀ jùlọ nípa ohun tí wọ́n ń wí. Ìwọ kò sì níí jẹ wọ́n nípá (láti gbàgbọ́). Nítorí náà, fi al-Ƙur’ān ṣe ìrántí fún ẹni tí ó ń páyà ìlérí Mi.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70