caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Ash-Shura, ẹsẹ 41

Mecca · revelation order 62 · 42:41

وَلَمَنِ ٱنتَصَرَ بَعْدَ ظُلْمِهِۦ فَأُو۟لَٰٓئِكَ مَا عَلَيْهِم مِّن سَبِيلٍ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelDájúdájú ẹni tí ó bá sì gbẹ̀san lẹ́yìn tí wọ́n ṣe àbòsí sí i, àwọn wọ̀nyẹn (tí wọ́n ṣàbòsí sí), kò sí ìbáwí kan kan fún wọn.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70