caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Ghaafir, ẹsẹ 80

Mecca · revelation order 60 · 40:80

وَلَكُمْ فِيهَا مَنَٰفِعُ وَلِتَبْلُغُوا۟ عَلَيْهَا حَاجَةً فِى صُدُورِكُمْ وَعَلَيْهَا وَعَلَى ٱلْفُلْكِ تُحْمَلُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah MikaelÀwọn àǹfààní (mìíràn) wà fún yín lára ẹran-ọ̀sìn. Àti nítorí kí ẹ lè dé ọ̀nà jíjìn tó wà lọ́kàn yín lórí (gígùn) wọ́n (kiri). Ẹ sì ń fi àwọn (ẹran-ọ̀sìn) àti ọkọ̀ ojú-omi gbé àwọn ẹrù.
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70