caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà As-Saaffaat, ẹsẹ 28

Mecca · revelation order 56 · 37:28

قَالُوٓا۟ إِنَّكُمْ كُنتُمْ تَأْتُونَنَا عَنِ ٱلْيَمِينِ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael(Àwọn ènìyàn) wí pé: “Dájúdájú ẹ̀yin l’ẹ̀ ń gba ọ̀tún wọlé sí wa lára (láti ṣì wá lọ́nà).”[1]
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70