caseriqÌwádìí ìtumọ̀ nínú Al-Ƙur'ān

Súrà Al-Qasas, ẹsẹ 74

Mecca · revelation order 49 · 28:74

وَيَوْمَ يُنَادِيهِمْ فَيَقُولُ أَيْنَ شُرَكَآءِىَ ٱلَّذِينَ كُنتُمْ تَزْعُمُونَ

Yoruba Translation - Abu Rahimah Mikael(Rántí) ọjọ́ tí (Allāhu) yóò pè wọ́n, Ó sì máa sọ pé: “Níbo ni àwọn akẹgbẹ́ Mi tí ẹ̀ ń sọ nípa wọn láì ní ẹ̀rí lọ́wọ́ wà?”
Looking for a topic? Try the meaning search — your question is scanned across all 6,236 verses.
Èdè — 70